Groupes virtuels Groupes virtuels
Optimisé par TakingITGlobal
TakingITGlobal

Accueil Accueil Communauté Groupes virtuels YORUBA PARAPO Messages   
Selectionnez la langue 

Groupe:
YORUBA PARAPO
  Ouvrir une session S'inscrire

Renseignements Membre(s) Messages Documents Articles relatifs

Message   Message Retour aux messages

De: "Olabisi Amao"
Sujet: E la mi loye!
Envoyé: Feb 2nd, 2006 - 06:23:07

  Mo Ki gbogbo omo egbe, ajo oni tu o.
Mo ni orebinrin kan ti o je omo ile Yoruba, ti o si n'gbero ati sa
lo si eyin odi tabi ki o pa ara re latari wipe awon obi re ko fe ki
o fe ololufe re ti i se omo alawo funfun.
Ore mi nikan ni awon obi re bi, won si tun ni owo lowo. Sugbon lati
igba ti ore mi ti balaga ko ri ife tooto ninu abasepo ohun ati awon
ore ti o ni siwaju afi igba ti okunrin alawo funfun naa de ti o si
fi ife ti ko ni abawon han si ore mi tobe gee ti awa ore toku n'ba
dunnu.
Kete ti awon obi re gbo wipe oyinbo ni omo naa fe fe ni won gbogun
ti, inu re si baje debi wipe ko fi okansi iwe re ni ile iwe giga ti
Unifasiti ti Obafemi Awolowo.
Oro naa t'oju su mi ni mo se ni ki nbeere lowo eyin ojogbon wipe
ona wo ni ki o gba. Se ki o fe omokunrin naa dandan ni tabi ki o wa
elomiran. E jowo e lawa l'oye nitori ko si asiko pupo fun
Emi ni tiyin tooto,
Olabisi


--
_______________________________________________
Surf the Web in a faster, safer and easier way:
Download Opera 8 at http://www.opera.com

Powered by Outblaze



TIG Groupes est un outil de communication gratuit de TakingITGlobal. TakingITGlobal se décharge de toute responsabilité de ces groupes discussions.
[ Conditions de service | Politique de confidentialité | Rapporter un problème ]