Groupes virtuels Groupes virtuels
Optimisé par TakingITGlobal
TakingITGlobal

Accueil Accueil Communauté Groupes virtuels YORUBA PARAPO Messages   
Selectionnez la langue 

Groupe:
YORUBA PARAPO
  Ouvrir une session S'inscrire

Renseignements Membre(s) Messages Documents Articles relatifs

Message   Message Retour aux messages

De: Henry Obarefe [ Profil ]
Sujet: Re: [ODUDUWA] Peli inu didun.
Envoyé: Oct 18th, 2005 - 06:17:16

  Olabisi, inumi dun lopolopo pe o da ra po mo awa egbe oduduwa lori TIG. aye wa fun e lati so owon ko won ti o ba fe lati so ti o ma mu oye wa fun wa. be o shey dara po mo wa Olodumare ma fun e loye ati agbara lati gbe awa omo yoruba larugbe ni e bi ki bi to ba wa. Lanre Araba ni oludari egbe yi, o le bere nko to ba fe mo, o ni epa lati dawun. Ose le kon si, Olabisi

Olabisi Amao wrote:Inu mi dun lopolopo lori akitiyan yin lati gbe eto ariyanjiyan kale
ni ede Yoruba. Mo gba ni adura wipe Olodumare yio je ki oseese.
Amin
Sugbon mo ni ibeere kan, Nje aye yio wa fun awon obinrin lati so
oro obinrin ati itoju awon omo owo lori eto naa?
Ti o ba ri be, mo ti gbaradi ni t'emi.
E mi ni tiyin tooto
Olabisi


--
_______________________________________________
Surf the Web in a faster, safer and easier way:
Download Opera 8 at http://www.opera.com

Powered by Outblaze


- - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - -
L"Araba

-------------------------------------------------------------------
Powered By TIG Groups http://groups.takingitglobal.org/
Group Archives: http://groups.takingitglobal.org/ODUDUWA
To unsubscribe, email ODUDUWA-unsubscribe (at) groups.takingitglobal.org




HENRY OBARICHES.


---------------------------------
Yahoo! Music Unlimited - Access over 1 million songs. Try it free.



TIG Groupes est un outil de communication gratuit de TakingITGlobal. TakingITGlobal se décharge de toute responsabilité de ces groupes discussions.
[ Conditions de service | Politique de confidentialité | Rapporter un problème ]