Groupes virtuels Groupes virtuels
Optimisé par TakingITGlobal
TakingITGlobal

Accueil Accueil Communauté Groupes virtuels YORUBA PARAPO Messages   
Selectionnez la langue 

Groupe:
YORUBA PARAPO
  Ouvrir une session S'inscrire

Renseignements Membre(s) Messages Documents Articles relatifs

Message   Message Retour aux messages

De: "lanre" [ Profil ]
Sujet: L'angbe J'ina . . .
Envoyé: Sep 21st, 2005 - 14:55:33

 















Eyim omo ati ara Ka'aro o'jire, she alafia ni gbogbo wa wa.Gbagede oro yi je anfani fun olukuluku wa lati da si oro t'onlo ni awujo wa, lati so ero ati edun okan wa bi o ti ri fun araye.Omo ati ara Yoruba, asiko to bayi lati gbe ede ati asha wa ni aruge, nitori bi onigba ba she gbe igba re ni won o ba gbe.Ni idi eyi, a ro yin lati da si eto yi nipa siso oro yala lori ilu Naijiriya tabi awon olori, tabi esin tabi awon eya ilu miran tabi ohunkohun ti o le mu wa tesiwaju nipa kiko ogbon, imo ati oye.E da si oro naa!





_______________________________________________
No banners. No pop-ups. No kidding.
Make My Way your home on the Web - http://www.myway.com




TIG Groupes est un outil de communication gratuit de TakingITGlobal. TakingITGlobal se décharge de toute responsabilité de ces groupes discussions.
[ Conditions de service | Politique de confidentialité | Rapporter un problème ]